IWURE OWURO: ADEOLA ADEPOJU & IOWU OGUNWALE
Page 1 of 1 • Share
- OduduwavoiceLv1: New Member
- Gender : Male
State : Ondo
Posts : 42 Posts Liked : 1
IWURE OWURO: ADEOLA ADEPOJU & IOWU OGUNWALE
A ku ojumo oni o gbogbo omo Yoruba ti m be l'agbaye L'eyi t'oku ki odun yi o pari, Mo p'ase irorun s'inu aye wa t'ako t'abo Nitori pe gbede bayii nii ro koko l'agbala Mo tun p'ase aseyori fun gbogbo adulawo O ti daju p'emu kii mu'rin ti l'agbede Bi koowa wa se n j'ade l'oni K'Eleduwa f'adun s'oro gbogbo wa, 'Tori owu kii la k'inu o b'oloko, Iran awon sekere kii ba won r'ode ibanuje, adun ni ti aadun l'ojo k'ojo, ladun-ladun laa ba n'ile oloyin, adun nii gbeyin ewuro, k'aye wa l'adun lat'owuro d'ale,
Ase n't'Edumare!

A ku ojumo oni o gbogbo omo Yoruba ti m be l'agbaye The "L" T read the wood, that pari, Mo p'ase irorun s'inu aye wa t'ako t'abo Nitori ti gbede baby ni ro koko l ' Agbala Mo Tun p ' ase aseyori fun gbogbo adulawo
They let you on p ' EMU AT CIL MU ' rin ti l ' Agbede Bi koowa wa se n j 'Ade L' oni K ' Eleduwa F ' Adun S ' oro gbogbo wa, ' Tori Owu ki la k ' inu o b ' Oloko, Iran awon sekere ki ba won r ' ode ibanuje, Adun ni ti adun l 'Ojo Ojo, k' Ladun-ladun no ba n ' ilename oloyin, Adun ni gbeyin ewuro, K ' aye wa l ' ADUN LAT ' owuro d ' Ale, Ase n 'T' Edumare!

Create an account or log in to leave a reply
You need to be a member in order to leave a reply.
Page 1 of 1
Permissions in this forum:
You can reply to topics in this forum